Wón fojú ọkùnrin tó n forúkọ adàjọ̀ lu jìbìtì ba ilé-ejọ̀

Charles Chukwudi
  •  Taofik Afọlabi

Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ti tẹ ọkunrin kan torukọ n jẹ Charles Chukwudi

  to  n lu awọn eeyan ni jibiti pẹlu ayederu iwe

  to ṣafihan ẹ gẹgẹ bi adajọ kootu ibilẹ to wa

 ni  Ẹpẹ ati Yabaa.

.Lara  awọn ayederu iwe ti wọn ba lọwọ ọkunrin

 naa ni: sitaapu ile-ẹjọ, iwe to ṣafihan ẹ bíi adajọ kootu ìbìlẹ to  wa ní Yabaa, iyẹn Oniidajọ CM Adeọla Ọlatunbọsun ati adajọ kootu ibilẹ

    to  wa ni  Ẹpẹ, Oniidajọ, A.B Ajifẹrukẹ .Bakan     naa  ni wọn tun ba ayederu kaadi idanimọ

      ọlọpaa ati fọto agbofinro lọwọ ẹ.

Read Also: Tinubu administration prioritises youth development – Akume

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, inu ọgba ile-ẹjọ Tinubu 

    to wa ni Erekusu Eko lọwọ ti tẹ ẹ, lẹyin

 tawọn oṣiṣẹ kootu naa funra si i pe onijibiti

   eeyan  ni. 

Gẹgẹ bi agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa

 .   nipinlẹ Eko, Benjamin Hundeyin, ṣe sọ, o ni

 lojuẹsẹ ti iwadii pari lori ẹ ni wọn ti gbe

  ọkunrin   naa lọ sile-

More posts